NI AFOJUSUN; OLORUN OLUGBEJA
NI AFOJUSUN KI O SI MAA SE ISE LATI SE ASEYORI; OLORUN YOO GBE IJA WA JA, AWA YOO SI WA NI ALAAFIA
NI AGBEKALE FUN OJO OLA RE; OLORUN OLUPESE
LAI SI AGBEKALE, O LEE SE ASEYORI; OLORUN LEE PESE FUN GBOGBO AINI RE
KO SI ENI TO LEE BA E GBE AYE RE; OLORUN OLUPAMON
TI O BA TI FI ARA RE FUN OLORUN, O KO NILO LATI BERU IKEKUN KANKAN
GBE IGBESE NI AKOKO; OLORUN ELEDA
LO OGBON TI OLORUN FUN O LATI YANJU AWON ISORO TI O BA SUYO; OLORUN ELEDA RE MON OHUN GBOGBO
KO SI ENI TI KO LEE SE ASEYORI; KOSI OJO ORI TO GA JU
IFARAENI JI ATI IHUWASI SE PATAKI SI ASEYORI; OLORUN BUKUN ABRAHAMU NI OJO OGBO RE
AWON ATEGUN SI ASEYORI; ABAYORI YIYAN BUBURU
IPINNU ATI AFOKANSI SE PATAKI SI ASEYORI; EKO LATI ARA LOTI ATI AWON OMOBINRIN RE
AGBEKALE SISE; ERE YIYAN OHUN TO BURU
LATI SE ASEYORI, O GBODO NI AGBEKALE RERE; EKO LATI ARA LOOTI
SISE ASEYORI; MELO NI IWO LE FI SILE?
O LEE SE ASEYORI TI O BA WO EBUN TI OLORUN FUN O; O DARA KI A MAA SE ALEJO