Ajọse ti ọmọ Iya ninu Ẹsin Islam
Share:

Listens: 1

About

Idanilẹkọ yii da lori awọn koko mẹta wọnyii: (i) Pataki asepọ jijẹ ọmọ iya ninu ẹsin. (ii) Ẹsan ti o wa fun asepọ ọmọ iya ninu ẹsin. (iii) Awọn nkan ti o maa nba jijẹ ọmọ iya ninu ẹsin jẹ.